- 歌詞
- アルバムリスト
Samuel Amazing Ayoade
-
Worship Experience 1
(instruments)
Oluwa, Oluwa wa Oruko Re ti n'iyin Ni gbogbo aye Oruko Re ti n'iyin to
*repeat
Esu gb'Oruko Re, o sa w'ogbo Aje gb'Oruko Re, o sa w'ogbo Talaba fi o we ninu awon Olorun Oluwa, Oluwa Omo to so mi di ominira Oruko Re ti n'iyi to Gbogbo aye n wariri won n teriba fun ntori もっと沢山の歌詞は ※ Mojim.com Oruko Re ti niyi to
Chorus: Oluwa... ... ...
Oju t'on so mi ti ko sun lo Eti t'on gbo mi ti mo ba kepe Abiyamo to pon mi ti ko sun lo Oruko Re ti n'iyi to Gbogbo aye n wariri won n teriba fun ntori Oruko Re ti n'iyi to
Chorus: Oluwa... ... ...
-
|